Eyin eeyan wa, didabe f’omobinrin ko dara o si kun fun lewu . Bi e ba mo enikeni ti o ngbero lati didabe omobinrin e lo so fun agbofinro ti o ba sun moo yin tabi ki e pé 08124670069.
E je ka jo sowopo lati dekun idabe’omobinrin